CULTURE

Foundation of our norms and values

TOURISM

Promoting our heritage

HISTORY

How it all started

ORIKI

ORIKI IDILE IDOFIN KWARA STATE
Dear Idofin People of Kwara State, a northern Yoruba town. Known your name - Oriki and Orile (Totem), the three Yoruba nomenclatures, that make Yoruba unique in the world. For example: Name; Adesola,? Oriki; Akanbi, Orile ( Totem) Iji. This show the originality of your forefather.
Example in the table below:

ORILE ( TOTEM)

ORIGINALITY TOWNS

Iji

Igbeti

Ebedi

Iseyin

Edu

Iresa

Aro

Latoosa family in Ibadan ( last Aare – Ona kakanfo of Yoruba land to fight? a war

Ogo

Ijesha

Elo

Erin-le

Iko

Olokun esin family Oyo – Ile

Eri

Oyan

Ogun

New line of Alaafin Oyo-Ile from Alafin Abiodun till recent and Bashorun descendants

Erin

Old-line of Alaafin, before Alaafin Abiodun

Okin

Olofa Of Offa And Oloro Of Oro Kwara State

Ade

Onikoyi (Osun)

Opo

Oyo - ile (Ikoyi)

Akinlalotun

Otun - Ekiti

Omo Olubisi

Tapa (Nupe)

Mojo

Oroki, Ake,Oya

Irese

Oko

Onife abure

Ile-Ife

Ojo, Ekan, Agbo, Oje etc.

ORIKI, AWO (AIYEKALE), OPONDA, (ODO –AGA) ,ILAFE? (ODO – AGA) IN IDOFIN ODO –ASHE.
Omo olubisi,omo alaro tin ?jogun esin,oso eyi ye tapa abiru ti emi, omo ajifowuro dana kulikuli, Eso were ara Ilodo nle Olubisi, Aye Tapa lowu mi, Boba di gba oku tapa mi o ni sin le.? Won ni e wo tutu owu , won ni ewa fara oyin, otutu owu sopo, Afara oyin sowon gogo, omo adada – ku- ada omo onilero mo na nmo, Adeegbee moseboti na mi le kan ni, omo onigunnu ari na wo, omo oni gunnu ariyo sese, omo onigunnu ti fi kulikuli sodun, Ewi fe ni ti o gbo, Ero feni ti o mo, eso fun wonpe tapa loni igunnu, ose were ara ilodo, olubisi omo alaro lo le sin.
ORIKI – ILOMO AYIEKALE (ODO- ASHE)
Iji, omo oye, oye ki pa ara igbeti, eni abi loye n pa, oginnitin nla, baba otutu. Ki wo we loye, iji olele. Ka boso sile, ka rin gboro le, ka wa weni to dape, ka weni toto foye soge. Kojo ko fo ginnitin yangan ?woja wo, Alogbo lomo arotutu tujuka, omo aroye nan eni –si – gban – gba. Omo agbo kakaki otutu- ma-beru.
ORIKI – EYIN – AFO AND OMO-ARO (IDOFIN –ASHE) AND OMO-ARO (IDOFIN – IGBANA)
Mojo – suke, omo amowo oko le lemi, aleeyaka lafo, okanna keke, omo abiti owo, owoiya o too na, ti babalo san pupo. Elefun dere, arofa siyan, ojo o pa ewa mi danu, o ba tete mewa ni ko mi, omo anide ni gbongan mojooya, oroso meji gba yigiyigi, omo osupa naja, omo oni gba aje. Omo ame lubo se yana , amu igba pet e won owo eyo, owo la mu molu eka gbin –laafo. Owo wa wale, eka wa wu sesese, omo ise ese obinrin ako, iya oje obinrin okanna o binrin okan na to ba wi iya n je oun, ?ile loti gbe iya-re wa. Bo nide kode lona kosin mi, kan osun mi lo tutu, omo ogede ose gun lafo, omo asopa di win. Mo satorin di monle? lafo. Atorin laa se loro, aki se egungun. Omo elubo esi bakaje. Tape nyo ape lenu taja nki ri bale.     

ORIKI OGBOLU IN AWO GROUP OF AIYEKALE IDOFIN ODO ASHE

Iko   ogbolu,   omo   rege   awo,   olugbede  Lona   an    ala,   enia   ti   o  se   omo   gbede    ala   to   ju   ba   mo , ko  mo   ba  won   de  ode  iteni,. Ile  omo  mini  kojo   ,  omo  aji  mogun  eru,  omo  boja    oja   giri,  ewo  ni   ominu   to   nda   ko   omo  ojo   se.

ORIKI OKE ORE IN AWO GROUP OF AIYEKALE IDOFIN ODO ASHE 

Owa   ajini   ara   amuyunke,   jeje  Nile  orota,   owa   lo   ti  nbo   lo   da   ide,   owa   lo   ti  nbo  lo da   baba,   owa   ajini   lo ti  nbo   lo   se   egungun   sekete   dani ,  egungun    sekete   to   un   ti   saworo.

A clocks and collectors said that when he replica watches liked the dead of night, he listened carefully to the ticking sound of rolex replica the mechanical texture of the clock, and the replica watches uk exhaustion of the day disappeared, and a great sense of uk replica watches satisfaction rose in the air.

ORIKI – IDOFIN (Ilegose,    Odo   eru,   Igbon)
Idofin mo-ba, omo ape wo ba ruko, omo aso kun je iyan odun, idofin moba , omo Akinla lo tun. Otun moba , osere, omo onireke agbejo , omo olodi atile mo, omo ireke arangan idun…………… etc.

 

 

ORIKI IGBANA

Ija omo oniku loyo
Omo onibebe aso
Omo egiga wata
Esu komoloto, eganran moko olore je
Omo aderinkunle niwowo
Omo akeke ta didun
Aso lodidi awo
Omo abidesu ara ale oyun
Ikoyi korioogunja oku pelebe bi abere de
Omo aroni ogbele, onikoyi onilegbe
Omo onikoyi eso

Oniku ogbo, ode amogbo morun
Omo elebura, akode ogun ode ara niju
Ode amoko obo jaraba iyan, iyan
Tan oko-obo ku daindain
Ode aderinkunle niwowo
Ode lagbagba ebido n kepe niwowo
Ode abi apo oogun, olori onibenbe
Ode alu ni kun erin, aworinde
Oworin omo eyo

 

 • ORIKI –EBIRIN (ODO-AGA)IDOFIN – ODO – ASHE
  Omo olope kangidi, omo amowo aya soungbogbo, ibi ope posi, ibe ni won ti polubu emu,
  ebirin oke.
  ORIKI – ILOBA- Idonfin Igbana
  Oloba bala, aba so gbo pon bi awo, abi sokoto kos u mefa nile alaro, a laro, ko gbudo re,
  sokoto mi ko gbodo junu, omo aya, amo e mu, keregbe dudu tori ope bo aiye, emu funfun
  lobe ninu re, omo keregbe, omo gba loba.
  ORIKI – IGBO-OGAN- Idofin Igbana
  Oba tete ma sikun oro kele, omo oro gbele sun oju emu lo, ajuba sekere kere doja loba,
  idi wewe lapa te, idi ile ke lapate osun, we we isedo moni otoja na, oto aya baba na dale
  koko.
  ORIKI –ILADE – Idofin Igbana
  Mo ladegun, omo oloran alagogo, atori pekun nisan, atori wewe paripo nise do, igbo awo
  ni won fi nlo.
  ORIKI- ILOMO – Idofin Igbana
  Omo oloran alagogo, aran adedun nisan, omo abi won ni sogun sogun, ila aran mo ni oti e
  lepo, osan aran mo ni oti e ni iyo, soka lole lo gba te la, omo abi mo bi eye madero wewe
  woja lose.
  ORIKI – EHIN – Agbe People: Idofin Igbana
  Omo amuyungesin, omo alahere owo, omo esu opin, omo oniyan awo, tipa lopin, omo bi
  okuje bi oku koje omo oniyan amu iyan re je , odo amu-kola yan ore, opin agiri, omo
  aribo kan seye, omo arugbo seyin ike funfun lenu ---
  ORIKI – O LUPO & MEMBERS IN : ILARO, IJALA, IGOBE IN IDOFIN
  IGBANA, AND ILE OLUPO; ODO-AGA – IDOFIN-ODO- ASHE
  Omo olupo alalu, omo alaelu joba, omo opere olupo poopo bi eni gundo ide, omo ta lala
  mo joye moje, omo ewewe las o ipo, ferege de laso awon oyan, omo olupo orira oba dudu
  igbo egi soboro nigbo edu, omo oyadosin oyadolu nile A deyemi, Ad eOba, omo akayemi
  yoyinoye olupo alealu, omo momu refe momu kemo, omo moferan kan logbo nile ilala,
  opere ina mesan ipo, opere onilaa jogbo ilosun, opere mo rewu sile doye----
  ORIKI – MOO – Idofin Igbana
  Ariki Omo oye lora, ora ni moo, magbele se bi oba, oke se ribiti sole lora, ariki me ni
  dere okun lomo kan, a riyo malulu ora, ariki ntaki, ma gbo ke ora dade, omo oju gbele oju
  yan gba oko, won ni o wa je olora o yo se se, won ni ko wa je olora, o bu erin si----
  ORIKI – ILEKAN – Idofin Igban
  Omo e lekan awinrin, omo benbe boju repete, ko nko a wewu eje, benbe njo, ena wa wo
  ran, bi to polo ti de atu aran monri, omo elubo esi ba ka je, ti ape nyo ape lenu, ti odede
  nje odede niya, ti ogedeaka ti ba aka sore---

Latest News

Loading...